Ajo NNPC wa ni kosi ooto ninu oro toja lori ero ayelujara twitter wipe alekun tiba owo petiro.

Iye owo, tajo NNPC nta epo petiro fawon alagbata ni ayipada o de ba o.

Ninu atejade tajo naa fisita nilu Abuja lo ti ro awon eeyan ile Nigeria lati mase beru tabie sojo pelu alaye pa igbese tin je gbigbe lati wojutu si oro ohun.

Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *