Ile igbimo asofin agba ile yi ti buwo lu idasile ajo to ni se pelu kiko ounje pamo fun ipese ounje lopo yanturu lorileede yi.

Saaju ki aba naa o to je bibuwolu, awon asofin naa lo ti koko gbena woju are won nipa agbara ti ile asofin ni loir ijiroro nipa idasile ajo naa.

Ni bayi na, abadofin naa je bibuwolu lasiko ti Aare ile asofin agba Dokita Ahmad Lawan founte lu abadofun naa.

Abadofin naa ni won gba wole leyin ti won tewo gba abo igbimo to wa fun ise agbe ati idagbasoke igberiko, eyi ti Abdullahi Adamu je alaga re.

Ninu oro tie, Senator Adamu salaye wipe ti ajo naa ba je dida sile tan, won yio se amuse ilana to wa fun kiko ounje pamo lona tile yi yio fi le ni igbokanle lasiko oda.

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *