News Yoruba

Onimo Kan Nipa Esin Islam Ke Sawon Omoleyin Kristi Tawon Musulumi Lori Ifesemule Alafia

Onimo kan nipa esin Islam, Ojogbon Afis Oladosu ti gbawon omo leyin Kristi atawon Musulumi nimoran lati maa bowo fun igbagbo arawon lona faaye gba Alafia ko joba yika ile Nigeria.

Ojogbon Oladosu, to je olori eka eko nipa imo Arts nile Eko Giga Fasity Ibadan, lo gboro amoran yi kale lakoko to kopa lori eto ile-ise wa kan lede geesi ta npeni Straight Talk ikanni  Premier F.M 93.5.

O to kasi pe, ko si idagbasoke kan dabi alara to le waye layika ti rukerudo esin ba ti n waye.

Nigba to n soro lori Pataki aawe Ramadan, Ojogbon Oladosu ro awon Musulumi, lati kasa baa se fi fun ni nipase yiyo Zakati ati Sadaka lakoko ati leyin osu mimo yii, eyi to ni won yoo gba ere re lodo Olorun Oba Allah.

Fawon Musulumi tenumo idi, to fi se Pataki lati teramo ise rere won lai fi takoko awe nikan se, nitori pe ere n be fun.

Kehinde/Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *