Yoruba

Egbe awon dokita nile iwosan U.C.H. Ibadan gunle iyanselodi alainigbedeke

Awon onisegun oyinbo to ngba imo kun imo, lati di akosemose nile iwosan nla UCH Ibadan ti gunle iyanselodi alainigbedeke.

Aare egbe awon onisegun oyinbo ohun ni ile iwosan nla UCH, Dokita Zakariyau Hussein fidi eyi mule lasiko to nba ilese Radio Nigeria soro.

Dokita Hussein t’okasi pe igbese naa waye lati fi aidunuwon han, nitori awon akinegbe won ti ko rowo osu gba lati osu kini odun yii

Dokita Hussein ko sai wa ro ijoba lati fii oruko awon dokita t’orokan sowo sajo toun risi ilana igbalode owo osu sisan fawon osise oba, IPPIS.

Elizabeth Idogbe/Titilayo Kupoliyi

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *