Yoruba

Ijoba Apapo Seleri Atunse To Ye Lawon Ile Iwosan Ile Yii

Aare Muhammadu Buhari ni ijoba apapo ti setan lati mu ironilagbara too ye baa eka eto ilera kake jado ile yii.

Aare Buhari eniti alakoso feto ilera, Dokita Osagie Ehanire n’ibi aprere kan nilu Jos n’ipinle Plateau, gboriyin fun ise takun takun awon dokita nile yii, laifi ti beka eto ilera seri se.

O wa bere fun atileyin egbe awon onisegun oyinbo nidi atungbedide eka eto ilera, eyiti yoo maa dahun si ibere ilera awon eeyan ile yii.

Aare nii, ijoba toun nlwaju ti nnawoo si idagabsoke eka naa fife awon ile iwosan toje tijoba apapo ati tipinle niti ibudo ifinwo tabi itoju ti ngbooro sii.

Nigba to wa n ro awon dokita lati fopin sii asaa iyanselodi lati pinwo ipaaseyin to nwaaye leka naa ati oofoo emi aare fikun pe ijoba apapo nilo atileyin gbogbo eeyan ile yii lati rialajupe eto ilera orileede nig naa kese jari.

Elizabeth Idogbe/Net

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *