News Yoruba

Iwole Awon Akekoo Ipinle Oyo Se Koriya Fawon Oluko Atawon Oga Agba Ile Iwe

Awon alase ati oludari awon ile-iwe gbogbo to n be nilu Oyo ati agbegbe re ti sapejuwe bawon akekoo se tuyaya jade loni lo sokan o jokan ile iwe won, je eyi to se atewogba to si wuni lori jojo, yato sib o se maa n waye tele, tiwon yoo maa rin kiri awon agbage lojo iwole won.

Akorinyin wa to lo yi ka awon ile-iwe kan, nijoba ibile Afijio atekun ijoba ibile ila oorun Oyo, jabo pea won oluko naa tin gbaradi feto eko kiko nitori bawon akekoo se tip o nilewe.

Oga agba ile ise girama Onitebomi, to wa lagbegbe Ilora nilu Oyo, Ogbeni Olusegun Ajayi, atemowo Gbenga Mosebolatan, salaye pe, beto iwole naa se, se Pataki si igbeaye awon akekoo.

Awon mejeeji wa kesi joba lati sami itona awon oju opopona to se koko ti yoo maa sise atona fawon onimoto lati kiwon duro fawon akekoo to ba fe fona.         

Net/ Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *