Banki apapo ile yi CBN ti ni kawon eyan awujo kiyesara lori ilokulo owo ile naijiria, to si sapejuwe owo naa gegebi eyi ton mu iwuri ba orile ede yi.

Alamojuto ile ifowopamo ile yi, leka ti won tin bojuto owo arabinrin Dorothy Onyene lo soro amoran yi nibi eto kan nilu awka, nipinle anambra.

O tun kii awon ontaja, agbe tofimo awon eyan ile yi yooku lati yago fun sise owo to was nita, lona ti kodara.

Arabinrin onyere, koroju si bi awon eyan sen kaa owo po lona ti ko dara, elomiran atun ko nkan si lara, o ni gbogbo irufe iwa yi ni ka ba ofin mu ti eni taje iwa ibaje yi ba se mo lori si le fie won osu mefa gbara tabi sisan owo itanran to je egberun lona adota naira.

Ololade Afonja/Net

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *