Ile igbimo asofin nbere fun atunto lori iwe ase to wa fun ebu ifopo, eyi ti won nfun awon ilese ifopo to wa labele nile Naijiria.

Nigba ti won ntewo gba aba kan lasiko ti agbenuso ile ogbeni femi gbajabiamila nlewaju ijoko ile, ni won ti ro ilese ton mojuto epo robi nile yi NNPC lati se atungbe ye wo okankan iwe eri, ti won situn le gba pada lowo ilese ti ko malo fun omin to jafafa.

Awon asofin tun ro ilese NNPC lati se atileyin to gbopan fun awon ilese to ti berre ise, lati le je ki won dogba pelu ori ti awon eyan nile naijirai nfe.

Bakana nile asofin tun pe ni dandan fun awon ile se epo roobi lati ri daju pe won fejo ase mule. Ololade Afonja/Net

Ile Igbimo Asofin Pe Fun Atunto Lori Iwe Ase Fun Awon Ebu Ifopo

Ile igbimo asofin nbere fun atunto lori iwe ase to wa fun ebu ifopo, eyi ti won nfun awon ilese ifopo to wa labele nile Naijiria.

Nigba ti won ntewo gba aba kan lasiko ti agbenuso ile ogbeni femi gbajabiamila nlewaju ijoko ile, ni won ti ro ilese ton mojuto epo robi nile yi NNPC lati se atungbe ye wo okankan iwe eri, ti won situn le gba pada lowo ilese ti ko malo fun omin to jafafa.

Awon asofin tun ro ilese NNPC lati se atileyin to gbopan fun awon ilese to ti berre ise, lati le je ki won dogba pelu ori ti awon eyan nile naijirai nfe.

Bakana nile asofin tun pe ni dandan fun awon ile se epo roobi lati ri daju pe won fejo ase mule.

Ololade Afonja/Net

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *