Igbákejì àrẹ lórílẹ̀ èdè yí, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo, tin bèrè fún àjọsèpọ̀ tó gúnmọ́ lárin ìjọba àpapọ̀ àti ti ìpínlẹ̀, káwọn ìpín ìjọba àwarawa lè kárí tolórí tẹlẹ̀mù àwọn èyàn orílẹ̀ èdè Nàijírìa.

Ó sọ̀rọ̀ yí lásìkò tí àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó ńsisọ lójú ilé ẹ̀kọ́ ẹ̀kọ́ni Marshal Inspectorate, ti wónkọ sípinlẹ̀ Delta.

Ọjọgbọn Ọsinbajo tẹnumọ́ kí ìbásepọ̀ tó gúnmọ́ kó wà lárin ẹ̀ka ìsèjọba bákanà lótún gbórínyìn fún ilésẹ́ ìjọba àti àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó, tó ti se ìdásílẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ méjì ọ̀tọ̀tọ̀ lárin ọdún kan sẹ́yìn.

Sherifdeen/Afọnja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *