Home Posts tagged àwọn ẹ̀ka ìjọba
Yoruba

Igbákejì àrẹ ńbèrè fún ìbásepọ̀ tó gúnmọ́ lárin àwọn ẹ̀ka ìjọba

Igbákejì àrẹ lórílẹ̀ èdè yí, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo, tin bèrè fún àjọsèpọ̀ tó gúnmọ́ lárin ìjọba àpapọ̀ àti ti ìpínlẹ̀, káwọn ìpín ìjọba àwarawa lè kárí tolórí tẹlẹ̀mù àwọn èyàn orílẹ̀ èdè Nàijírìa. Ó sọ̀rọ̀ yí lásìkò tí àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó ńsisọ lójú ilé ẹ̀kọ́ ẹ̀kọ́ni Marshal Inspectorate, ti Continue Reading