Ijoba apapo ile yi ti sope oun ti n gbalero lati je ki igbese lilo eroja afefe gaasi fun idana se dogbandogba laarin araalu, gegebi are igbese lati madinku ba biwon se n gegi nigbo, afefe bibaje ati nemi se n sofo latara lilo awon eroja epo petirolu.

Nigba to n soro nibi ipade kan, Akowe Agba to n ri soro isowo isedeede Epo petrol, Ogbeni Ahmed Bobboi, salaye pe ijoba tun setan lati gbe awon eroja epo robi, papa julo, epo petrol gbawon oju ona oko oju irin koja yika orileede yi.

Ko sai tokasi pe, bawon se n samulo epo betrolu nile yi, ti madinku de ba sise deede re pelu ida ogbon si ida ogorun o le dii tiwon n beere fun lorileede yi, gege bi ipenija aito awon ohun amayederun.

Ko sai soo di mimo pe, ti eroja idana afefe gasi ba kari owo rira koni gunpa, ti gbogbo eeyan yoo si lanfani si yika ile, Nigeria, atipe adinku yoo deba isowo gegi nigbo jojo to fimon iniran tawon eeyan nkoju latara ina igi dida.

Bee lo si fikun pe, erongba boba yi tihan sawon ajo ijoba gbogbo, tiwon si ti n gbe igbese lati wa ni bamu pelu aba ofin ile-ise to n ri soro epo petrol nile yii, PIB.

Folakemi Wojuade/Omolola Alamu

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *