Agbarijo egbe awon osise nipinle Ekiti ti ni awon o gba bi ijoba ipinle naa se fe yowo ninu sisan owo osu tuntun to kere ju ati atunse owo osu.

Agbarijo egbe awon osise naa to ni ninu egbe awon osise NLC, TUC ati eyiti o wa fun idunadura, JNC, ni won ti sepadepo alatilekun mori se pelu Gomina Kayode Fayemi lori ipo ti oro aje ipinle naa wa, ti won w ape fun fifun awon ile eko giga tijoba ipinle naa ni woo ati gbo bukata won.

Atejade latodo alaga egbe NLC, Ogbeni Kolapo Olatunde, Alaga TUC, Sola Adigun ati ti JNC, Kayode Fatomiluyi leyin ipade naa so wipe awon egbe yi ni igbiyanju eyikeyi lati tubo muki awon osise ati awon to kudie kato fun nipinle Ekiti di akurete ni awon o fowo si.

Ti won wa ni yiyo ninu sisan owo osu tuntun to kereju fawon osise ati awon atunse owo osu ko bojumu ati wipe iwa ika gbaa ni.

Oluwayemisi Dada

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *