Abala keji Synod elekeejo re, ti Diocese ariwa Ibadan ijo Anglican ti wa sopin pelu ipe sijoba apapo lati wa ojutusi itajesile, aibaradogba, sisegbe, iyan ati bowo oja se nfojoojumo gbenu soke ti o ti nsakoba fun ilosiwaju igbayegbadun oun oro aje ile yi.

Nigbati o n baa won oniroyin soro leyin opin Synod ati isin idupe to waye ni Bishop Akinyele Memorial Anglican Church, Aare Synod tutun se Bishopu agba Diocesi ariwa Ibadan.

Eni owo segun Okubadejo so wipe ile yi ni Olorun bukun fun pelu oniruru oro alumoni ti won fi nsofo latipas eto aabo to mehe.

Ojise Olorun naa w ape fun ipade apero apapo lati wa ojutu sawon isoro wonyi to war o awon omo ile yi lati teramo adura ki ohun gbogbo lee di sise.

Saaju ninu iwaasu re, Bishopu Diocese Kwara, Eni Owo Sunday Adewole ti ro awon omo ile ye lati ni igbekele nmu Olorun nigba gbogbo.

Eni Owo Adewole tun kesi awon adari ile yi lati rii pe idajo Ododo rese wale ki won si ri wipe won pin awon oro alumo ile yi kari tolori telemu.

Famakin/Dada

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *