News

Aare Buhari Ti Pase Pe Kiwon Gbe Asia Ile Yi Wa Si Idaji Opo Lati Fi Bu Ola Fun Awon Omo Ologun To So Emi Won Nu

Aare Orileede yi Muhammadu Buhari ti pase pe, won gbodo gbe Asia ile Nigeria wa si idaji opo ni gbogbo awon eka ile-ise ijoba, bere latoni yi lo titi di ojoru ose yi.

Igbese yi lo waye lati fi bu ola fun Oga Agba fun ile ise omo ologun ile yi, Ogagun Agba Ibrahim Attahiru atawon osise omo ologun mewa mi ti won so emi won nu ninu isele ijamba oko baalu to wa ye lojo Eti tokoja nilu Kaduna.

Bee laare situn ya ojo oni soto gege bi isinmi lenu ise fawon osise omo ologun ile yi.

BANJO/WOJUADE

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *