Igbimo ile-ise, Aare ti won gbekale lori oro arun covid-19 ti kede sisawari awon arin-rin ajo bi aadorun topo ninu won je awon omo ile Nigeria atawon eeyan ile okeere eyi to sapejuwe airi won gege bi ohun to lewu feto ilera ile Nigeria.

Atejade kan talaga igbimo naa ti tunse akowe sijoba apapo orileede yii, Ogbeni Boss Mustapha, soodi mimo pe, awon eeyan aadorun naa ti gbogbo won ti tan yi ka orileede yi ni won tako ofin tiwon fisita fawon arin-rin ajo to ba n wo orileede yi wa lati ile India, Turkey ati Brazil.

Gege batejade ohun tun se wipe, awon eeyan naa toruko ati awon iwe irinna won wa ninu atejade tiwon fisita fun igbimo ile ise Aare ohun niwon rapala wo ile Nigeria.

  BANJO/WOJUADE

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *