Yoruba

Ilé Asòfin Àgbà Kò Jálè Láti Yan Onochie Gégé Bíi Alákoso Àjo INEC

Ilé ìgbìmò asòfin Àgbà ti kò jálè láti fowósí ìyànsípò Lauretta Onochie gégé bí Alákoso fájo elétò ìdìbò ilè yìí, Inec.

Alága ìgbìmò náà, Kabiru Gaya so nínú àbò rè pé, Onochie ni kò kún ojú òsúnwòn tíjoba àpapo làkalè.

Tílé Asòfin àgbà òhún sì dìbò tako ìyànsípò rè.

Wojuade