Adarí ilé ìgbìmò asòfin kejì, ògbéni Fémi Gbàjàbíàmílà , sopé  oùn kòní kópá nínú eyikeyi Aba ofin , ti yoo pa àwon Ile ise iroyin lenu mi.

 Ògbéni Gbàjàbíàmílà tun salaye pe, iyato wa laarin agbekale awon Ilana ateele ati pipa Ile ise iroyin lenumo.

Nibi Apero kan to waye nilu ibadan lo ti soro yii di mimo.

O ni bíótilèjépé ofin faaye gba ominira oro, àmó Toni ijoba naa ni ise láti se labe ofin, feto isejoba to jiire

Igbese yii lo waye nibamu pelu awuyewuye bawon eeyan se n benu atelu atunse ofin to de ise iroyin ati tajo to n ri soro igbohunsafefe Nile yii, eyi ti Ògbéni Segun Odebunmi sagbateru re, Nile ìgbìmò asòfin naa wa salaye pe, oun yoo tubo sise iwadii Lori boya won satunse si iwe ofin Ile ise iroyin lati fi pawon lenu mo ni tabi beeko.

Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *