News Yoruba

Ile Asofin Ipinle Oyo so wipe Kosi otito ninu iroyin kan pe won se ipade ni bonkele

Ile Asofin Ipinle Oyo ti soo di mimo pe ko si ohun to jo ipade pajawiri lojo eti ko koja nitori ati buwolu iwe eyawo to je ogorun kan billionu naira, eyi ti Gomina Seyi Makinde bere fun.

Ile Asofin naa salaye wi pe o se Pataki lati tan imole si awuyewuye pea won asofin tun ti buwolu iwe eyawo miin nikoko laarin awon omo ile asofin naa metala.

Alaga igbimo tee koto ile Asofin naa to wa fun eto iroyin, Ogbeni Kazeem Olayanju soo di mimon pe metalelogun ninu awon omo ile asofin naa mejilelogbon lo wa nikale lasiko ijoko pajawiri to waye:

O salaye wi pe saaju ni ile asofin naa ti sun ijoko won si ojo ketadinlogbon osu yi, sugbon ti won pe ipade pajawiri lati fi fun igbese naa.

Igbese owoya tii se ogorun kan billion naira ti won fowosi fun Gomina ni won fe fi ya owo nile ifowopamo agba ile yi, lati odun to koja, sugbon ti won ko tete pari igbese re, ko to dip e banki agba ile yi tun fun won ni anfaani naa se pade.

Kehinde/Salaudeen

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *