Ilé ẹjọ́ tó fi ilẹ̀ olóminira Benin sebujoko yio gbọ ẹjọ́ lóni bóyá kí wọ́n fi ajìjàgbara fún ìdásílẹ̀ orílẹ̀ èdè Oodua nì Olóyè Sunday Adeyẹmọ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Sunday Igboho sọwá síll yí.

Agbẹnusọ fún Olóyè Sunday Igboho, Ọlayọmi Koiki ẹnití ó sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ fáwọn oníròyìn sọ wípé àná ló yẹkí ìgbẹ́jọ́ náà wáyé àmọ́ tí ìwọ́de àwọn ọmọ yoruba ní Cotonu paginínà rẹ̀.

Lálẹ̀ ọjọ́ ajé ọ̀sẹ̀ yí ni ọwọ́ tẹ ẹ ni pápákọ̀ òfurufú tó wà ní Cotonu lásìkò tó ńgbìyànjú àti tẹ ọkọ̀ létí lọ sórílẹ̀ èdè Germany pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀.

Femi Dadamola

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *