Yoruba

Ijoba Apapo Sefilole Lilo Ibudo Iforukosile Awon Oko Nile Yii

Ijoba Apapo Orileede yi ti sefilo lilo ibudo iforuko sile awon oko to nbe nile yi lati gbogun ti biwon se so ile Nigeria di ibiti won le maa da aloku oko si ati iwa fayawo.

Alakoso feto isuna, ataato gbogbo, Hajia Zainab Hammed lo soro yi di mimo lakoko to n side eto ilaniloye olojo kan lori igbese naa fawon toro kan n’ipinle Kano.

Hajia Zainab salaye pe, won ti so ile Nigeria di budo tiwon ti n ji oko gbe, gege bo se je pe opo awon oko to n be lorileede yi ni ko se akosile re, leyi to je ko soro lati sawari re tiwon ba jigbe.

Adele Oludari Ajo Asobode ile yii, lekun B, Ogbeni Uba Mohammed sope, liana naa yoo pinwo aiseto abo, tiwon yoo sit un maa rowo pawole labele papa julo lori latara awon oko.

Folakemi Wojuade/Mosope Kehinde

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *