Yoruba

Ajo NCDC Sekolo Lori Ibesile Arun Onigbameji

Ko din lawon eeyan bi egberin merindinlogun to ti jOlorun nipe latara arun onigbameji tamo wi Cholera lawon ipinle mejilelogun atolu ilu ile wa Abuja, ninu awon eeyan to le legberun lona mokanlelogbon tarun cholera naa ba fin ra laarin gbedeke osu meje seyin.

Oludari agba patapata fun ibudo to n risi ikapa arun olokanojokan nile yi, NCDC, Dokita Chikwe Ihekwazu, to siso loju oro yi nilu Abuja, salaye pe, aisawon omi to se bumu buwe, mima se igbonse soju taye, aiseto imototo ayika to munadoko, to fimo aini imototo wa lara awon nnkan to n mu ki arun naa poosi gege bi Dokita Ihekwazu se wipe, o se Pataki fawon ijoba ipinle, lati tete gunle awon igbese fi wa ojutu soro arun onigbameji naa, papa julo nibamu pelu ipese omi to mo gaara, eto gbalekale ti to fese rinle atawon ona lati kappa arun cholera tanwi naa ko sai gbawon omo orileede yi nimoran lati tere lo maa sayewo are won nile wosan nikete tiwon be kefin awon arun bi igbonse gbuuru, eebi ati ko ma reeyan lago ara.

Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *