Yoruba

Awon Toro Kan Kesijoba Ipinle Oyo, Lori Gbigbawon Osise Eleto Ilera Imototo Ayika Sise Lopo

Bakanna, bi ina eto gbaleko doti se n jo ajo reyin lawon apa ibikan nipinle Oyo, niwon ti bedi re ru aito awon osise eleto ilera imototo ayika lawon ijoba ibile eyi to n pe fun akiyesi kiakia.

Awon olugbe toro kan nilu Oyo to ba oniroyin ile-ise Radio Nigeria soro tokasi pe, iwonba awon osise eleto ilera to wan le lowolowo bayi nipinle ni niwon to ton kan lati koju bawon eeyan se n poosi ati bidagbasoke se n bawon ilu nla-nla.

Nigba to n sapejuwe ipo teto gbalekodoti naa wa gege bi eyi to n koni lominu, Alhaji Wahab Ogundele, so pe ohun iyalenu loje pe opo awon ijoba ibile to n ba nipinle Oyo, niko lawon osise eleto ilera imoototo ayika to to marun niye gege ba se wipe, eyi lo sokunfa bi ise itopinpin awon osise eleto ilera naa muna doko, lori oro imototo ayika.

 Ko sai soodi mimo pe, bi opin yoo ba deba igbese sise igbonse soju taye, tijoba yoo si se aseyori lori re, ijoba ipinle Oyo nilo lati gbawon osise Eleto Ilera loposi sawon ijoba ibile, pelu afikun pe, odun 2006 nijoba ti gbawon osise eleto ilera imototo ayika sise keyin.

Oguntona/Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *