Igbimo to ga julo lori oro esin Islam nile Nigeria, labe akoso Aare igbimo naa, eni tii tun se Sultan tilu Sokoto, Alhaji Muhammad Sa’ad Abubakar ti benu ate lu iwa isekupani to waye nilu Rukuba, nijoba ibile Ariwa Jos, Ipinle Plateau.

Ninu atejade naa ni igbimo yi ti toka si atejade ti Gomina Ipinle Plateau at ti pinle Ondo ti soo di mimo pe oro naa ko ri bi awon eeyan se lero re, ati pe kii se awon to fara kaasa ajalu naa ni won gbero re fun, ati pe kawon eeyan yago fun sise idajo lowo are eni.

Igbimo naa wa tenumo pe, ko si omo eeyan Kankan to ye ki won maa gbero anuru si nipa fifi esin tabi eya boju, o se afikun e pea won n topinpin iwadi to n lo lori esun naa ati pe won yoo rii daju pe idajo ododo waye.

Ewe, egbe awon omoleyin Christy nile yi (CAN) eka tipinle Plateau naa sapejuwe iwa ipaniyan naa gege bi eyi ti ko bojumu.

Atejade ti alaga egbe naa nipinle Plateau Polycarp Lubo fi sita ro awon agbofinro pe ki won wa awon obayeje naa ni awari.

Frcn Net/ Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *