Yoruba

Omo Egbe Agbaboolu Super Eagles Daku Lori Papa Lasiko Idije Egbe Agbaboolu To Wa Nile okeere

Omo egbe agbaboolu Super Eagles to tun je agbaboolu ile okeere ninu egbe Bordean Star, Samuel Kalu lo daku solu papa lana lasiko ifesewonse pelu iko egbe agbaboolu Marsulle.

Kalu, eni odun metalelogun lo n gbiyanju ati daabo bo ojuile egbe agbaboolu re, ko to dii pe o subulule.

Awon akegbe re lo sare sugba re, amo leyin itoju awon eleto ilera lo tun na idije naa lo.

Amo sa, won fi elomin ropo re leyin iseju mejo.

Net/ Salaudeen

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *