News Yoruba

O Le Leedegbeta Awon Odo To Janfani Ise Ninu Isin Keta Eto N. Power

O le leedegbeta awon odo kaakiri ile yi ti won ti gba sise labe eto N power isin keta iha akoko re.

Nibi ifilole re nilu Abuja, alakoso foro ifomoniyanse, amojuto isele ijamba, Hajiya Sadiya Umar-Farouq ni liana gbangba laranta ni won lo lati mu won to war o awon olukopa lati samulo anfani ti won fun won.

Nigbati o nsoro, alakoso keji foro ile ise nla-nla, okoowo ati idokowo, Hajiya Mariam Katagun o ro awon odo naa lati je asoju rere, ki won si lo anfani ti won ni lati tubo fi ni imo sii.

Alakoso foro iroyin, Alhaji Lai Mohammed ni eto naa lati igbati won ti da sile ti sise bu irinse ati dekun aini suuru awon odo.

Alhaji Muhammed eniti akowe agba ile ise ijoba foro-iroyin omowe Ifeoma Anyanwutak soju fun tenumo ipinu ijoba lati kase ise  ohun, o si nile.

 

FRCN, Abuja/Owonikoko

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *