Igbakeji Aare, ileyi, Ojogbon Yemi Osinbajo ti ro awon ile ifowopamo atawon eka eto enawo min lati maa teramo awon ise akanse ti yoo se ayipada ily, bi kiko ilegbe to fimo awon oun amusagbara to se so dotun lona ti yoo fi pese ise pelu mimu adinku ba ise oun osi.

Ojogbon Osinbajo soro naa nilu Abuja o salaye pe eka ifowopamo ati eto enawo lo ti n kopa to joju ninu oro aje latodun to pe.

Gegebi igbakeji Aare se wi, o ni asiko ti to wayi ki eka ohun gunle awon nkan ti yoo sayipada oro aje.

Ojogbon Osinbajo woye pe didojuko eto enawo ile kiko je eyi to se koko.

Ewe, nigba to gun eka ifowopamo ni kese, lori kikopa ninu eto kiko ilegbe lopo yanturuti joba apapo gunle, igbakeji Aare safikun oro pee ka eto enawo ko ti kopa to joju lori eto ile kiko ti yoo wulo fawujo.

         

Alamu/Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *