Igbakeji Aare, ileyi, Ojogbon Yemi Osinbajo ti ro awon ile ifowopamo atawon eka eto enawo min lati maa teramo awon ise akanse ti yoo se ayipada ily, bi kiko ilegbe to fimo awon oun amusagbara to se so dotun lona ti yoo fi pese ise pelu mimu adinku ba ise oun osi. Ojogbon Osinbajo soro […]Continue Reading
Lameeto awujo, Ogbeni Henry Odeh ti tenumo idi to fi yen ki atunto o waye lagbo oselu ati eto oro aje orileede yii. Ogbeni Odeh foju oro yi lede lasiko to n kopa lori eto Straight Talk lede gegebi nileese wa Premiers fun. Lameeto awujo naa salaye wipe o se Pataki fun ile Nigeria lati […]Continue Reading