News Yoruba

Oga Agba Ajo Agunbaniro Sekilo Fawon Odo To N Sin Rulu Lorin Jijijna Si Se Oselu Lagbegbe Ti Won Wa

Oga agba ajo agunbaniro nile Nigeria, Ogagun Shuaibu Ibrahim ti sekilo fawon odo ton sinru ilu lati jina si sise oselu lawon aye ti won bag be won lo jinjina si iwa odaran ori ero ayelujara, ilokilo ogun olor ati  fayawo omoniyan.

Oro imoran ohun lowa ninu ibanisoro re lasiko ipari eto ifinimole fawon agunbaniro ipin B abala keji.

Ninu ibanisoro ohun ti alamojuto ajo naa fun ipinle Osun, Ogbeni Adewale Adegoke gbe kale, Oga agba ohun ko sai tun gba awon agunbaniro niyanju lati maa bowo fun asa awon eeyan agbegbe ti won ti n sinru ilu.

O ni nise loye ki won maa gunle awon eto tole mu idagbasoke baa won agbage ti won wa kole se igbelaruge isokan ati ibagbepo Alafia ile Nigeira.

Ogagun Ibrahim war o won lati mu awon idanileko ti won gba lasiko eto ifinimole olose meta ohun lokunkundun ki won le da duro lowo ara won yago fun wiwa ise oba ti o si nile kaakiri

Akinola/Olaopa

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *