Ijoba apapo ti fowo idaniloju soya fawon osise re pe, oun yo ri daju pe dogban-dogba de ba owo osu awon osise re, ko to di ipari odun 2021 ta wa yi.

Olori osise n’ile yi, Omowe Folasade Yemi-Esan lo je koro yi di mimo n’ilu Abuja.

Omowe Yemi-Esan so pe ala to wa laarin owo osun awon osise lo ye ki won gbe yewo ni komonkonmo.

O tokasi pe iyato to wa laarin owo osun eka kan is omin, lo po, to si ye ki idogba deba.

Olori Osise se lalaye pe igbimo ti won se agbekale, ni oun  je okan lara omo egbe, pelu afikun pe ileese to n risi isuna, ise and igbanisise naa wa lara igbimo ohun.

Omolola Alamu/Ololade Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *