Ijoba ipinle Oyo so pe oun ti se ifilole igbimo ti yo ma sise lori kiko egbin laarin ipinle Oyo.

Igbimo ohun loni igbimo alase lati ilese eto ilera, to n risi ipale egbin mo ileese to n risi oro ayika atawon ileese miran toro naa kan gbon-gbon.

Gegebi atejade eyi ti alakoso foro ayika ati on alumoni, Ogbeni Abiodun Oni so pe ona atele to yan ranti ni ijoba ipinle yo gbe sita laipe.

Ogbeni Oni fowo idaniloju soya pe igbiyanju nlo lowo lati ri daju pe ipenija lofi kiko egbin kuro loju opopona atawon agbegbe to wa nita gbangba ni yo dopin laipe laijina.

Omolola Alamu/Alolade Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *