Àarẹ Muhamadu Buhari nìrètí wàpé yóò sọ̀rọ̀ lọ́la-òde yíì níbi àpàdé àpérò àyípadá ojú-ọjọ́ àti ìpàdé àláfìa ní Glasgow, Scotland.

Àarẹ yóò sọ̀rọ̀ lórí àwọn ìpinu ilẹ̀ yíì láti gbógunti àyípadà ojú-ọjọ́ tófimọ́ síse àseyọrí àfẹnukò ojú-ọjọ́ ilẹ̀ pari.

Olùranlọ́wọ́ àgbà pàtàkì sáàrẹ fọ́rọ̀ ìròyìn àti ìbáráàlù-sọ́ọ̀rọ̀, Mallam Garba Shehu sọ èyí nínú àtẹ̀jáde ninu Abuja.

Net/Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *