Àjọ tó rísí ìpeniye ónjẹ àtòògùn nílẹ̀ yíì, NAFDAC, ti gbé àwọn ilésẹ́ tó ńpèsè omi mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n pa nótorí àigbéwọ̀n tóò àwọn ilésẹ́ náà.

Olùdarí àgbà NAFDAC, Ọ̀jọ̀gbọ́n Mojisọla Adeyẹye ẹnitó sọ èyí nípasẹ̀ asojú àti olùdarí ẹ̀ka ọ̀rọ̀ àwùjọ, Ọ̀mọ̀wé Jimọh Abubakar sàlàyé pé, ìgbésẹ́ náà níse pẹ̀lú àisí ìmọ̀tóòtóò tópéye àwọn ilésẹ́ ọ̀hún.

Ọ̀ jọgbọn Adeyẹye wá sèkìlọ̀ fáwọn ilésẹ́ tó ńpèsè omi nílẹ̀ yíì, láti máà gbé ìgbésẹ̀ tóòye páàpáà àyíka tóò le kúrò.

Ọga-àgbà àjọ NAFDAC, ohun, kò sài wá gba àwọn ilésẹ́ náà níyànjú láti ma se ohun gbogbo níbamu pẹ̀lú òfin, yóò kojú ìjìyà tó bá yẹ.

Net/Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *