Adari Ile Asofin Ipinle Osun, Ogbeni Timothy Owoeye ti soo di mimo pe won gbodo se agbekale ona ti agba yio fib a ona ipawowole sapo ijoba inpinle naa ni gbogbo ona.

Ogbeni Owoeye soro yi di mimo lasiko tawon ileese ijoba n salaye bi won se fen a eto isuna won fodun 2022, nile asofin to wa nilu Osogbo.

Adari ile asofin naa tenumo pe igbese ohun gbodo je gbigbe nidi ati le je kagbaga o ba eto oro aje ipinle naa.

O gba awon ileese ati lajolajo ti je tijoba ipinle naa nimoran pe ki won maa tunbo pawo sapo ijoba bee lo ro ileese to n ri si ona ipawowole pe kawon wa a ma kaare ninu oju e won lati di gbogbo ona ti apo ijoba ba n gbaajo.

Saaju ninu oro re asaaju awon iko naa eniti tuu se alamojuto eto oro aje ati liana eto isuna nipinle Osun, Ojogbon Olalekan Yinusa salaye wipe ijoba ko ni kaare nidi ati rii pe won tele liana eto isuna gbogbo ni sii sen tele.

Ojogbon Yinusa eni to toka sip e ijoba ipinle won se aseyori nidi ati ti wipe won se amulo ida metadinlogorin eto isuna odum 2020 pelu ida metadinlogorun fodun 2021 pelu akinyesi wipe ko ye kijoba fe ronu ati fowo kun owo ori taraalu nsan.

Adekoya / Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *