Egbe  awon onimo isegun oyinbo lorileede yi, ANPMP, n fe kawon omo ile Nigeria maa mojuto ilera won nipa didaabobo ara won lowo ajakale arun HIV/AID.

Alaga egbe naa nipinle OGUN, Dokita Adeneye Kusimo lo pepe yi nilu Abeokuta fun ti isami ayajo arun AIDS lagbaye fun todun yi to akori e da lori “fopin si aisedogbadogba, fopin si arun AIDs fopin is ajakale arun.

Dokita Kusimo tun pe fun agbega eto ipolongo nipe pe kawon omo ile yi maa fi ife han yato fun yiya awon to ba ni arun AIDS niposin,, o tenumo pe iberu titakete seni to ba ni arun naa lo maa n je ki opo beru ati lo se ayewo lati fi le gba itoju to peye lori arun naa.

Wa kesi awujo agbaye pe ki won pese eto isuna to peye pelu eto ijoku, ati pe ki iwuri o wa fawon oloyun lati maa lo fun ipade alaboyun dedee.

Dokita Kusimo tun pe fun ifowosowopo gbogbogba lori ati gbogun ti arun naa, ati pe kamu eeyan awujo gbaruku tie to itoju of, to n waye fawon to ti ni arun naa lara.

Folarin / Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *