Gómìnà ìpínlè oyo, onímò èro Seyi Makinde tí ro àwọn ẹlẹ́sìn Islam láti máà tesiwaju lórí àjọṣepò tó dán mọran pẹ̀lú ìjọba kole sekunlowo fún ètò isejoba rere.
Ó soro náà nilu Ìbàdàn lásìkò ìpàdé àpapò ègbé akojopo àwọn ẹlẹ́sìn islam tekun Gúsù ìwọ orun, ìyẹn Muslim Human of South West Nigeria, MUSWEN, eleekefa irue nilu Ìbàdàn.
Gómìnà Makinde ti Olubadanmoran rẹ foro tó jẹ́ mo tesin islam, Alhaji Abdul Rasheed – Azeez soju fún ṣàlàyé pé, irúfé ajosepo bẹ yóò faaye gba igbora ẹni ye fún ìdàgbàsókè ìgbàgbépo àlàáfíà.
Èwe, nígbà tó n sọ̀rọ̀ lórí àkòrí tí wọ́n pè ní aiseto àbò nílè Nàìjíríà, ipa rẹ lórí ìhùwàsí ọmọniyan, olubanisoro níbi ètò náà túnṣe alamojuto ilé ìṣe olopa tẹ́lẹ̀rí omowe Yinka Balogun lodi ọrọ ṣíṣetó abo mọ aìdúró rẹ ìlànà isejoba ohun ailegbera tó ìjọba lórí àgbékalè àwùjọ tó dùnwọn ètò ẹ̀kọ́ tó mo yàn lórí ohun ìdàgbàsókè àwọn odo.
Omowe Balogun kò sai tún tọ́ka sí ìwà ajebanu tó ti di bárakú láwùjọ ileyi ohun àlàfo ńlá tówà laarin àwọn oloro àti àwọn tó kudie káto fún gẹ́gẹ́ bí nkan tó ń fa bile yí kòṣe n dele ìlérí.
Ṣáájú nínú ọrọ Ààrẹ ẹgbẹ́ MUSWEN, Alhaji Rasaki Oladejo loti tenumo pàtàkì ironi lágbára àwọn tí ò rowo orí fún wiwojutu soro àwọn tókù díè káto fún láwùjọ.

Adebisi /Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *