Home Posts tagged Gómìnà Makinde
News Yoruba

Gómìnà Makinde fe káwọn ẹlẹ́sìn Islam ní àjọṣepò tó dán mọran pẹ̀lú ìjọba

Gómìnà ìpínlè oyo, onímò èro Seyi Makinde tí ro àwọn ẹlẹ́sìn Islam láti máà tesiwaju lórí àjọṣepò tó dán mọran pẹ̀lú ìjọba kole sekunlowo fún ètò isejoba rere.Ó soro náà nilu Ìbàdàn lásìkò ìpàdé àpapò ègbé akojopo àwọn ẹlẹ́sìn islam tekun Gúsù ìwọ orun, ìyẹn Muslim Human of South West Nigeria, Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Makinde sekìlọ̀ fáwọn èèyàn tó ń gbìyànjú láti domi àláfìa ọ̀yọ́ rú

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sèkìlọ̀ fáwọn èèyàn láti yàgò kúrò nídi àwọn ìgbésẹ̀ kan, èyí tó lè yọrísí fífi tìpá tikuuku yo yan kan kúrò nípò tàbí léwọn kúrò nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Ìkìlọ̀ yíì ló wáyé níbamu pẹ̀lú dàrúdápọ tó wáyé láàrin àwọn àgbẹ̀ àtàwọn darandaran kan lágbègbè òkè-ògùn nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Gómìnà Makinde […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Makinde ti sèlérí láti sèpàdé pẹ̀lú alákoso ilésẹ́ ọlọ́pa ípinlẹ̀ ọ̀yọ́

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sèlérí láti sèpàdé pẹ̀lú alákoso fún ilésẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbéni Joe Nwachukwu, láti ridájúpé ìgbésẹ̀ tóòyẹ jẹ́ gbígbé fún àbò gbogbo-gbò.  Ó sọ̀rọ̀ yíì nílu ìbàdàn, lásìkò tó ńbá àwọn olùfẹ́húnúhàn tó ń gbèèrò láti dàànà sún ilésẹ́ ọlọ́pa Testing ground Idi-apẹ ìbàdàn.  Lásìkò tó ńbá […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Makinde ní òun ò ti si ilé ìwé padà

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti ní ojú ò kán òun láti sílẹ̀ kùn àwọn ilé ìwé padà àyàfi tí òun bá gbọ́ ìmọ̀ràn láti ẹnu àwọn akọ́sẹmọ́sẹ́. Ó sọ̀rọ̀ yi níbi àkànse ìjóko ilí ìgbìmọ̀ asòfin láti sàmì ayẹyẹ ọdún kan tí wọ́n fi ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ yi elẹ́kẹsan lọ́lẹ̀. Ó […]Continue Reading