Níbamu pẹ̀lú akitiyan rẹ̀ láti dábo bo ìlànà gbígbé ètò ọrọ̀ ajé gbabomin, ìlera àti ìgbáyégbádùn ọmọnìyàn ló mú kíkọba àpapọ̀ orílẹ̀dè yíì, fọwọ́sí ìlànà ètò àbò tuntun nílẹ̀ Nàijírìa.

Alákoso kejì fọ́rọ̀ àyíká, Oloye Sharon Ikeazor tó sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì nílu Abuja, sọpé àgbékalẹ̀ ìlànà ètò àbò tuntun náà àtàgbékalẹ̀ èróngbà láàrin ọdún 2022 sí ọdún 2026 ni latiridaju pé, ètò àbò tó péye wà lórí àyíká àti ètò ìlera ọmọnìyàn kúrò lọ́wọ́ àwọn ewu tóníse pẹ̀lú rẹ̀.

Alákoso kejì náà tún fi k;alàyé rẹ̀ pé lẹ́yìn ọ̀kanòjòkan àyẹ̀wò tó wáyé lórírẹ̀, láwọn tọ́rọkàn ti buwọlu lósù kẹsan, kó tó dipé wọ́n gbé kawájú ìgbìmọ̀ alásẹ láti fòntẹ̀lù.

Folakemi Wojuade   

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *