Ijoba Ipinle Osun nfe kawon egbe tinu nbi atawon omobibi agbegbe igbaye, faaye gba Alafia ju ohun koun lo.

Arowa yii lo tele gbomisi omiooto to waaye lagbegbe igbaye, arungbungbun ijoba ibile Odo-Otun, lojo aika lori oro oro-aje.

Alakoso foro iroyin ati ibaralu soro, Arabirin Funke Egbeode enito rawo ebe naa ni ilu ilesa, nii, awoo naa ti je kikapa, tawon osise eleto abo siti wa lagbegbe ohun lati fese abo emi ati dukia mule.

Arabirin egbemode ni awoo oye kise ahun titun lawon agbegbe kan, amo oni Gomina Adegboyega Oyetola ti fowosi pe, awon oye kanakan o gbodo pagidina Alafia.

Ijoba ti waa ro awon araalu atawon egbe tinunbi lati gbe ejo won lo sodo awon alase torokan, kiwon si dehin nidi iwa sise idajo lowo-araani.

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *