Tawon eeyan ile yii yoo ba jegbadun isejoba awarawa o se Pataki kawon adari fopin si asa imotara eni nikan kiwon mu isejoba rere lokunkundun.
Alufa St. Paul Anglican Church, Odo Ona Apata Ibadan, Venerable Adeyemi Jesulola, lo soro yii lasiko to nkopa lori eto ilese Premier F.M 93.5 lede gessi straight talk.
Venerable Jesulola nii, orilede yii lolorun fi awon oun alumoni atawon olopolo pipe eda jinki eyi toto fun idagbasoke alailegbe amo toni anilo awon adari rere toke wuloo botiye.
Bakana loni aini ife orileede eni je isorokan gboogi ton sakoba fun awon adari atawon alatele won nile yii, eyi toomu ki eto ilanilooye sojuse ati ife orilede eni sepataki fawon eeyan ile yii.
Venerable Jesulola wa samulo akoko towayii, pe fun wiwa nkan sesi, igbese bawon eeyan se n sakuro nile yii lo soke-ookun fonje ojo won
Ojise Olorun yii, ko sai waa ro awon omo leyin krist lati mase lo akoko yii fun jije mimu nikan amo, kiwon naa owo ore sawon tokudie katoo fun nibamu pelu ibi krist.


