Alakoso foro abele, Ogbeni Rauf Aregbesola ni, ogba atunse towa ni agbegbe Oloju-Oro, Olomi nilu Ibadan yoo bere sin je sisamulo losu keta odun yii.

Alakoso so eyi lasiko to sabewo si, Ogba Atunse, Agodi, Ibadan ati agbegbe Olomi.

O salaye pe, Ogba atunse Olomi yi tise tife pari lori re, yoo gba to awon eeyan towa logba atunse bii egberin.

Ogbeni Aregbesola ni sisi ibudo yi yoo madinku ba, akunfaya ibudo atunse Abolongo ati Agodi.

Ogbeni Aregbesola ti ko pase wiwo gbogbo awon ibudo, ibuso itaja towa layika ibudo atunse Agodi.

Orileede Nigeria lo ti nkoju Oniru-ru isele ikolu awon ibudo atunse yi ti tenu lolo yi si waye ni Ile-Ife ipinle Osun.

Olarinde/Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *