Olujabo bere idaraya se nlo lori papa titun se, agbenu so nigbakan ri fegbe agbaboolu Shooting Star, Ogbeni Jubril Arowolo, ti fenu sipe igbese to dara gba ni, gbigba awon akonimogba labele fegbe agbaboolu Super Eagles.

Ogbeni Arowolo so leyi di mimo lasiko to nko pa lori eto ilese Premier FM 93.5, Straight Talk.

Ogbeni Arowolo enito gboriyin fun ise takun-takun akonimogba egbe agbaboolu Super Eagles, Augustine Eguavan nibi ifesewonse Afcon 2021 to n lo lowo.

O salaye pe gbigba awon akonimoogba latoke okun da bi fifi ohun alumoni sofo ni.

Ogbeni Arowolo salaye pe akonimogba yi koju osuwon lati mu iko naa de ipele asekagba ohun gbigba ife-eye, tosi fi ireti re han pe iko agbaboolu Super Eagles yoo se daadaa nibi ifesewonse won pelu Guinea Bissau loja ode-yi.

Ogbeni Arowolo wa ro ijoba lati dakun dabo mu agbega ba ere-idaraya lese kuku.

Ogbeni Arowolo ni kikobiara otun sere boolu yio mu owo to nrogun sapo ijoba ru gogo si.

Kehinde / Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *