Gomina ipinle Oyo Onimoero Seyi Makinde ti siso loju ise siso akanse opopona oni kilometre mesan ole die Oke Ogun Poly, ilu Saki Ilesa-Ibariba di onibeji.
Gomina Ahmadu Fintiri ti ipinle Adamawa tii se alejo pataki nibi eto naa, gboriyin fun Gomina Makinde fun ise akanse ohun atawon nkan amayederun miran laifi ti ipenija oro aje se.
Oki Gomina Makinde ku orire fun botise duro po pelu awon eyan awujo pelu atokesi pe ipolongo re lati so igbe di igboro lo tin fi mimuse pelu kika opopona tofi ni aseyori.
Nigba ton soro nibi eto ohun eyi to waye ilewe gbogbonise Oke Ogun Saki Gomina Makinde tenumo pe ise akanse opopona ni yo mu agbega deba eto oro aje to yo si se atona fun ipinle Oyo ode oni
Ofikun pe isejoba re ko ni fowo oselu mu eto idagbasoke ipinle Oyo, towoja re yo is lo yika ipinle yi, kuro ni ilu Ibadan nikan ti se olulu ipinle Oyo.
Ololade Afonja/Iyabo Adebisi


