Gomina Banki agba ile Nigeria CBN, Ogbeni Godwin Emefiele ti ro awon ile ise to n risi ipese iresi nile yi lori igbawole eto ti banki naa gbe kale fun gbigbon wo si ipawo wole nile Nigeria.

Ogbeni Emefiele soro yi nibi eto kan to waye nipinle Kano.

O salaye pe irufe eto bee yoo tun ro ipese iresi labele lagbara ti yoo sit un pese ise.

Gomina Banki agba ohun wa tenumo Pataki kawon ile ise to n pese iresi nileyi gunle ni ogbin re ki ounje ohun le posi.

Ogbeni Emefiele salaye pe irufe igbese bee yoo tun seranwo fun ipese iresi latodo awon agbe alaroje pelu ajosepo Banki agba ileyi to fi mo egbe awon ologbin iresi atawon min.

Ogbeni Emefiele wa fmin idaniloju han sawon ile ise to n risi ipese iresi lori ikunlowo fun ipese ounje naa nileyi

Adesanya/Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *