Igbakeji aare ile yi, Ojogbon Yemi Osinbajo ti ro awon illse iroyin pe ki won parapo gbogun ti iroyin eke gbigbejade.

Ojogbon osinbajo  pepe yi nilu nilu Eko pelu alaye wi pe igbese bonkele ninu  eto akoso  ijoba ko dunkooko mo bo se ye ki ko maa o ri nile yi mo, bi ko se iroyin eke to gbode kan.

Igbakeji aare wa mu imoran wape ki awon ileese  iroyin fowo lile mu oro iroyin eke nipa bi won se je ileese to ye ko maa fonrere ododo.

Ojogbon Osinbajo salaye wi pe bi awon ileese iroyin se je eka kerin ninu eto ilu, o ye ki won maa la awujo loye lori ise digbadigba at sise deede.

Nigba ton salaye pataki awon ileese iroyin nile Nigeira nidi eto aseyori ijoba awarawa, igbakeji aare ro awon oniroyin pe ki won tunbo diro mo siso ododo nigba gbogbo.

Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *