Igbakeji aare ile yi, ojogbon Yemi Osinbajo ti sope ile yi ko ni pe so oro ipenija eto abo ton ba finra di afiseyin teegun alare fiso. Igbakeji Aare soro yi lasiko ti egbe kan to n satileyin fun aare muhammadu Buhari sabewo si nilegbe aare L Abuja.Gege bosewi, awon ipenija ton bale yi fira […]Continue Reading
Igbakeji aare ile yi, Ojogbon Yemi Osinbajo ti ro awon illse iroyin pe ki won parapo gbogun ti iroyin eke gbigbejade. Ojogbon osinbajo pepe yi nilu nilu Eko pelu alaye wi pe igbese bonkele ninu eto akoso ijoba ko dunkooko mo bo se ye ki ko maa o ri nile yi mo, bi ko se […]Continue Reading
Igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo sope pelu ipenija to nkoju ile yii, lati ogota odun toti gba ominira re, o se Pataki lati fojusun ojo-iwaju pelu ireti. Ojogbon Osinbajo so eyi nibi eto idanileko Egbe NASFAT, fawon odo, pelu akori “Isokan, Alafia Ati Aseyori Ile Nigeria”. Igbakeji Aare sodi mimo pea won odo ni ojuse […]Continue Reading