Oluko agba, Ojogbon Hafis Oladosu  ti toka si opo jagidijagan ti won n fi esin boju lati se gege bi eyi to kun fun iwa imotara eni nikan.

Ojogbon Oladosu, eni tii se oga agba leka eko Arts nile Eko Giga Fasiti Ibadan foju oro yi jade lasiko idanileko awon ojogbon nile eko giga fasiti naa, eyi tii se irinwo ati mokandinlaadorun irue ti akori re da lori Oro Esin Islam ati Ede Larubawa.

Oluko agba ile eko giga fasiti naa salaye wi pe opo rogbodiyan esin ni ko se bee ni oro igbagbo ninu, bi ko se lati wa agbara ati oro aye.

Ojogbon oladosu, tie ka ede larubawa ati esin Islam nile Eko Giga Fasiti Ibadan, tun kesi gbogbo awon toro kan  ati ijoba pe ki won yowo ilana to ba le se akoba fun igbora.

Fasasi/Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *