Home Posts tagged Àarẹ Mùsùlùmí fàmọ̀ràn síta lórí ìlànà áàbò lásìkò ọdún iléyá
Religious
Sáàjú ọdún iláyá, áàrẹ mùsùlùmí fún gbogbo ilẹ̀ yorùbá, Ẹdó àti Dẹlta, Àlhájì Daud Akinsọla ti gba àwọn mùsùlùmí lámọ̀ràn láti tẹ̀lé gbogbo àwọn ìlànà áàbò láti dènà àrùn covid-19 láwọn ibùdó ìjọsìn. Àarẹ fọ̀rọ̀ àmọ̀nràn yi síta nígbàtí ó ńgba àwọn ikọ̀ àjọ tó ńrísí ìtanijí ará ìlú sí ojúse wọn, NOA, ẹ̀ka ti […]Read More...
Load More