-
Onimo eto ilera ro awon omo Nigeria lati gba abere ajesara covid-19
Siwaju sii, ijoba apapo yoo se idasile ero to nseranwo feemi eda, oxygen, ni gbogbo ipinle towa lorileede yi, gege bi ara ona lati koju wahala ti ero naa nfa lawon ibudo ifiniwo at itoju. Alaga, iko amuseya ijoba apapo farun covid-19 ptf, titu se akowe agba sijoba apapo, Ogbeni Boss Muustapha, so eyi nilu…