Home Posts tagged agbega
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ láti mágbega bá iná ọba

Ìgbìmọ̀ alásẹ ìjọba àpapọ̀ ti buwọlu isẹ́ àkànse mẹ́rìndílógún lójúnà àti mú àgbéga báà iná mọ̀nà-mọ́ná nílẹ̀ yíì. Alákoso fóun àmúsagbára, Àlhájì Abubakar Aliyu sọ̀rọ̀ yíì fáwọn oníròyìn lẹ́yìn ìpàdé ìgbìmọ̀ alásẹ èyítí igbákejì ààrẹ ilẹ̀ yíì ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Osinbajo darí rẹ̀ nílu Abuja. Ó níì Continue Reading