Ọkọ̀ agbepo kan tó kún fún epo bẹntirol ti da ẹrù rẹ̀ nù lágbègbè Dangote, tó wà ní ìdígba Ilọra lópopónà másọsẹ̀ ọ̀yọ́ sí ìbàdàn, èyítí ó ti fi àwọn awakọ̀ àti olugbé ibẹ̀ sínú ewu. Akọ̀ròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria ríì gbọ́ wípé awakọ̀ epo nà ni wọ́n ti gbé lọ sí iléwòsàn lásìkò tó […]Continue Reading